Òwe 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọwọ́ tó dilẹ̀ ń sọni di òtòṣì,+Àmọ́ ọwọ́ tó ń ṣiṣẹ́ kára ń sọni di ọlọ́rọ̀.+ Òwe 23:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí ọ̀mùtí àti alájẹkì yóò di òtòṣì,+Ìtòògbé yóò sì sọni di alákìísà.