Sáàmù 131:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 131 Jèhófà, mi* ò gbéra ga,Bẹ́ẹ̀ ni ojú mi ò ga;+Bẹ́ẹ̀ ni mi ò máa lé nǹkan ńláńlá,+Tàbí àwọn nǹkan tó kọjá agbára mi.
131 Jèhófà, mi* ò gbéra ga,Bẹ́ẹ̀ ni ojú mi ò ga;+Bẹ́ẹ̀ ni mi ò máa lé nǹkan ńláńlá,+Tàbí àwọn nǹkan tó kọjá agbára mi.