Òwe 11:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Abanijẹ́ ń sọ ọ̀rọ̀ àṣírí kiri,+Àmọ́ ẹni tó ṣeé fọkàn tán* máa ń pa àṣírí mọ́.*