Róòmù 12:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ “tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ; tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní nǹkan mu; torí bí o ṣe ń ṣe èyí, wàá máa kó ẹyin iná jọ lé e lórí.”*+
20 Àmọ́ “tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ; tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní nǹkan mu; torí bí o ṣe ń ṣe èyí, wàá máa kó ẹyin iná jọ lé e lórí.”*+