-
Òwe 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kò yẹ kí òmùgọ̀ máa gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ;
Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ pé kí ìránṣẹ́ máa ṣe olórí àwọn ìjòyè!+
-
-
Òwe 26:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Bíi yìnyín nígbà ẹ̀ẹ̀rùn àti òjò nígbà ìkórè,
Bẹ́ẹ̀ ni ògo kò yẹ òmùgọ̀.+
-