2 Pétérù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ohun tí òwe tòótọ́ náà sọ ti ṣẹlẹ̀ sí wọn: “Ajá ti pa dà sídìí èébì rẹ̀, abo ẹlẹ́dẹ̀ tí a ti wẹ̀ ti ń yíra mọ́lẹ̀ nínú ẹrẹ̀.”+
22 Ohun tí òwe tòótọ́ náà sọ ti ṣẹlẹ̀ sí wọn: “Ajá ti pa dà sídìí èébì rẹ̀, abo ẹlẹ́dẹ̀ tí a ti wẹ̀ ti ń yíra mọ́lẹ̀ nínú ẹrẹ̀.”+