Jóòbù 36:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó ń fa àwọn ẹ̀kán omi sókè;+Omi inú àwọsánmà* rẹ̀ ń di òjò; Jóòbù 38:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ta ló gbọ́n débi tó fi lè ka àwọn ìkùukùu,*Àbí ta ló lè da omi inú àwọn ìṣà omi ojú ọ̀run,+ Jeremáyà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà tó bá fọhùn,Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+ Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+ Yorùbá Publications (1987-2025) Jáde Wọlé Yorùbá Fi Ráńṣẹ́ Èyí tí mo fẹ́ràn jù Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania Àdéhùn Nípa Lílò Òfin Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ JW.ORG Wọlé Fi Ráńṣẹ́ Fi Ráńṣẹ́ Lórí Email
27 Ó ń fa àwọn ẹ̀kán omi sókè;+Omi inú àwọsánmà* rẹ̀ ń di òjò; Jóòbù 38:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ta ló gbọ́n débi tó fi lè ka àwọn ìkùukùu,*Àbí ta ló lè da omi inú àwọn ìṣà omi ojú ọ̀run,+ Jeremáyà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà tó bá fọhùn,Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+ Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+
37 Ta ló gbọ́n débi tó fi lè ka àwọn ìkùukùu,*Àbí ta ló lè da omi inú àwọn ìṣà omi ojú ọ̀run,+ Jeremáyà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà tó bá fọhùn,Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+ Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+
13 Nígbà tó bá fọhùn,Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+ Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+