1 Tẹsalóníkà 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ fi ṣe àfojúsùn yín láti máa ṣe jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́,+ ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀,+ kí ẹ máa fi ọwọ́ yín ṣiṣẹ́,+ bí a ṣe sọ fún yín, 1 Pétérù 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ ká má ṣe rí ẹnikẹ́ni nínú yín tó ń jìyà torí pé ó jẹ́ apààyàn tàbí olè tàbí aṣebi tàbí torí ó ń tojú bọ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀.+
11 Ẹ fi ṣe àfojúsùn yín láti máa ṣe jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́,+ ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀,+ kí ẹ máa fi ọwọ́ yín ṣiṣẹ́,+ bí a ṣe sọ fún yín,
15 Àmọ́ ká má ṣe rí ẹnikẹ́ni nínú yín tó ń jìyà torí pé ó jẹ́ apààyàn tàbí olè tàbí aṣebi tàbí torí ó ń tojú bọ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀.+