-
Ẹ́sítà 7:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Torí náà, wọ́n gbé Hámánì kọ́ sórí òpó igi tó ṣe fún Módékáì, ìbínú ọba sì rọlẹ̀.
-
-
Sáàmù 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àwọn orílẹ̀-èdè ti rì sínú kòtò tí wọ́n gbẹ́;
Ẹsẹ̀ wọn ti kó sínú àwọ̀n tí àwọn fúnra wọn dẹ pa mọ́.+
-
-
Oníwàásù 10:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ẹni tó ń gbẹ́ kòtò lè já sínú rẹ̀;+ ẹni tó sì ń wó ògiri olókùúta, ejò lè bù ú ṣán.
-