Òwe 25:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Kò dára láti jẹ oyin ní àjẹjù,+Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ògo kankan nínú kéèyàn máa wá ògo ara rẹ̀.+ Jeremáyà 9:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Kí ọlọ́gbọ́n má ṣe yangàn nítorí ọgbọ́n rẹ̀;+Kí alágbára má ṣe yangàn nítorí agbára rẹ̀;Kí ọlọ́rọ̀ má sì yangàn nítorí ọrọ̀ rẹ̀.”+ 2 Kọ́ríńtì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí kì í ṣe ẹni tó ń dámọ̀ràn ara rẹ̀ ni a tẹ́wọ́ gbà,+ bí kò ṣe ẹni tí Jèhófà* dámọ̀ràn.+
23 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Kí ọlọ́gbọ́n má ṣe yangàn nítorí ọgbọ́n rẹ̀;+Kí alágbára má ṣe yangàn nítorí agbára rẹ̀;Kí ọlọ́rọ̀ má sì yangàn nítorí ọrọ̀ rẹ̀.”+