Jóòbù 1:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà sì bi Sátánì pé: “Ṣé o ti kíyè sí* Jóòbù ìránṣẹ́ mi? Kò sí ẹni tó dà bíi rẹ̀ ní ayé. Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni, ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.” 9 Ni Sátánì bá dá Jèhófà lóhùn pé: “Ṣé lásán ni Jóòbù ń bẹ̀rù Ọlọ́run ni?+
8 Jèhófà sì bi Sátánì pé: “Ṣé o ti kíyè sí* Jóòbù ìránṣẹ́ mi? Kò sí ẹni tó dà bíi rẹ̀ ní ayé. Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni, ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.” 9 Ni Sátánì bá dá Jèhófà lóhùn pé: “Ṣé lásán ni Jóòbù ń bẹ̀rù Ọlọ́run ni?+