-
Jẹ́nẹ́sísì 39:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àmọ́ Jèhófà wà pẹ̀lú Jósẹ́fù.+ Ìyẹn mú kó ṣàṣeyọrí, ọ̀gá rẹ̀ tó jẹ́ ará Íjíbítì sì fi ṣe alábòójútó ilé rẹ̀.
-
-
Òwe 17:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ìránṣẹ́ tó ní ìjìnlẹ̀ òye yóò di ọ̀gá lórí ọmọ tó ń hùwà ìtìjú,
Yóò sì pín nínú ogún bí ọ̀kan lára àwọn ọmọ.
-