Kólósè 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ohunkóhun tí ẹ bá ń ṣe, ẹ ṣe é tọkàntọkàn* bíi pé Jèhófà* lẹ̀ ń ṣe é fún,+ kì í ṣe èèyàn,