Dáníẹ́lì 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí náà, ọba, kí ìmọ̀ràn mi rí ìtẹ́wọ́gbà rẹ. Yí pa dà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ nípa ṣíṣe ohun tó tọ́, kí o sì yí pa dà kúrò nínú ìwà burúkú rẹ nípa fífi àánú hàn sí àwọn aláìní. Ó ṣeé ṣe kí nǹkan túbọ̀ lọ dáadáa fún ọ.’”+
27 Torí náà, ọba, kí ìmọ̀ràn mi rí ìtẹ́wọ́gbà rẹ. Yí pa dà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ nípa ṣíṣe ohun tó tọ́, kí o sì yí pa dà kúrò nínú ìwà burúkú rẹ nípa fífi àánú hàn sí àwọn aláìní. Ó ṣeé ṣe kí nǹkan túbọ̀ lọ dáadáa fún ọ.’”+