Òwe 23:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Má ṣe wà lára àwọn tó ń mu wáìnì lámujù,+Tàbí àwọn tó ń jẹ ẹran ní àjẹkì,+ 1 Kọ́ríńtì 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ. Ẹgbẹ́ búburú ń ba ìwà rere* jẹ́.+
20 Má ṣe wà lára àwọn tó ń mu wáìnì lámujù,+Tàbí àwọn tó ń jẹ ẹran ní àjẹkì,+ 1 Kọ́ríńtì 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ. Ẹgbẹ́ búburú ń ba ìwà rere* jẹ́.+