ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 15:13-15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Níkẹyìn, Sámúẹ́lì dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, Sọ́ọ̀lù sì sọ fún un pé: “Kí Jèhófà bù kún ọ. Mo ti ṣe ohun tí Jèhófà sọ.” 14 Àmọ́ Sámúẹ́lì sọ pé: “Kí wá ni ohùn agbo ẹran tó ń dún yìí àti ohùn ọ̀wọ́ ẹran tí mò ń gbọ́ yìí?”+ 15 Ni Sọ́ọ̀lù bá sọ pé: “Ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ámálékì ni wọ́n ti mú wọn wá, nítorí àwọn èèyàn náà dá agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran tó dára jù sí,* láti fi wọ́n rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ; àmọ́ a ti pa àwọn ohun tó ṣẹ́ kù run.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́