ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sítà 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Wọ́n fi àwọn lẹ́tà náà rán àwọn asáréjíṣẹ́ sí gbogbo ìpínlẹ̀ tó wà lábẹ́ àṣẹ ọba, láti fi pàṣẹ pé kí wọ́n pa gbogbo àwọn Júù, kí wọ́n run wọ́n, kí wọ́n sì pa wọ́n rẹ́, lọ́mọdé lágbà, àwọn ọmọ kéékèèké àti àwọn obìnrin, lọ́jọ́ kan náà, ìyẹn lọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kejìlá, oṣù Ádárì,+ kí wọ́n sì gba àwọn ohun ìní wọn.+

  • Ẹ́sítà 3:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn asáréjíṣẹ́ náà jáde lọ kíákíá+ bí ọba ṣe pa á láṣẹ; wọ́n gbé òfin náà jáde ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.* Ọba àti Hámánì wá jókòó láti mutí, àmọ́ ìlú Ṣúṣánì* wà nínú ìdàrúdàpọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́