-
Òwe 26:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ẹni tó ní ahọ́n èké kórìíra àwọn tó fi ń bà jẹ́,
Ẹnu tó ń pọ́nni sì ń fa ìparun.+
-
-
Róòmù 16:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nítorí irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ kì í ṣe ẹrú Olúwa wa Kristi, bí kò ṣe ti ohun tí wọ́n fẹ́ jẹ,* wọ́n máa ń fi ọ̀rọ̀ dídùn àti ọ̀rọ̀ ìpọ́nni fa ọkàn àwọn tí kò fura mọ́ra.
-