-
Ìṣe 19:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Nígbà tí akọ̀wé ìlú náà wá mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn náà dákẹ́, ó sọ pé: “Ẹ̀yin èèyàn Éfésù, ta ni nínú gbogbo èèyàn ni kò mọ̀ pé ìlú àwọn ará Éfésù ni ìlú tó ń bójú tó tẹ́ńpìlì Átẹ́mísì ńlá àti ère tó já bọ́ láti ọ̀run?
-