Sáàmù 37:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+ Ìfihàn 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Máa yọ̀ nítorí rẹ̀, ìwọ ọ̀run+ àti ẹ̀yin ẹni mímọ́,+ ẹ̀yin àpọ́sítélì àti wòlíì, torí pé Ọlọ́run ti kéde ìdájọ́ sórí rẹ̀ nítorí yín!”+
34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+
20 “Máa yọ̀ nítorí rẹ̀, ìwọ ọ̀run+ àti ẹ̀yin ẹni mímọ́,+ ẹ̀yin àpọ́sítélì àti wòlíì, torí pé Ọlọ́run ti kéde ìdájọ́ sórí rẹ̀ nítorí yín!”+