Òwe 14:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni tí kì í tètè bínú ní ìjìnlẹ̀ òye,+Àmọ́ ẹni tí kò ní sùúrù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.+ Òwe 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn ohun tí òṣìṣẹ́ kára gbèrò láti ṣe máa ń yọrí sí rere,*+Àmọ́ ó dájú pé gbogbo àwọn tó bá ń kánjú yóò di aláìní.+
5 Àwọn ohun tí òṣìṣẹ́ kára gbèrò láti ṣe máa ń yọrí sí rere,*+Àmọ́ ó dájú pé gbogbo àwọn tó bá ń kánjú yóò di aláìní.+