Òwe 18:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọkàn gíga ló ń ṣáájú ìṣubú,+Ìrẹ̀lẹ̀ ló sì ń ṣáájú ògo.+ Mátíù 18:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ bí ọmọ kékeré yìí ni ẹni tó tóbi jù lọ nínú Ìjọba ọ̀run;+ Fílípì 2:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jù bẹ́ẹ̀ lọ, nígbà tó wá ní ìrí èèyàn,* ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ó sì di onígbọràn títí dé ojú ikú,+ bẹ́ẹ̀ ni, ikú lórí òpó igi oró.*+ 9 Torí ìdí yìí gan-an ni Ọlọ́run ṣe gbé e sí ipò gíga,+ tó sì fún un ní orúkọ tó lékè gbogbo orúkọ mìíràn,+
4 Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ bí ọmọ kékeré yìí ni ẹni tó tóbi jù lọ nínú Ìjọba ọ̀run;+
8 Jù bẹ́ẹ̀ lọ, nígbà tó wá ní ìrí èèyàn,* ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ó sì di onígbọràn títí dé ojú ikú,+ bẹ́ẹ̀ ni, ikú lórí òpó igi oró.*+ 9 Torí ìdí yìí gan-an ni Ọlọ́run ṣe gbé e sí ipò gíga,+ tó sì fún un ní orúkọ tó lékè gbogbo orúkọ mìíràn,+