Sáàmù 62:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bákan náà, ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ jẹ́ tìrẹ, Jèhófà,+Nítorí o máa ń san kálukú lẹ́san iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.+ Lúùkù 18:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Olúwa wá sọ pé: “Ẹ gbọ́ ohun tí adájọ́ náà sọ, bó tiẹ̀ jẹ́ pé aláìṣòdodo ni! 7 Ṣé kò wá dájú pé Ọlọ́run máa mú kí a dájọ́ bó ṣe tọ́ fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ tí wọ́n ń ké pè é tọ̀sántòru,+ bó ṣe ń ní sùúrù fún wọn?+
6 Olúwa wá sọ pé: “Ẹ gbọ́ ohun tí adájọ́ náà sọ, bó tiẹ̀ jẹ́ pé aláìṣòdodo ni! 7 Ṣé kò wá dájú pé Ọlọ́run máa mú kí a dájọ́ bó ṣe tọ́ fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ tí wọ́n ń ké pè é tọ̀sántòru,+ bó ṣe ń ní sùúrù fún wọn?+