-
Òwe 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kò yẹ kí òmùgọ̀ máa gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ;
Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ pé kí ìránṣẹ́ máa ṣe olórí àwọn ìjòyè!+
-
-
Oníwàásù 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Mo ti rí àwọn ìránṣẹ́ tó ń gun ẹṣin àmọ́ tí àwọn olórí ń fẹsẹ̀ rìn bí ìránṣẹ́.+
-
-
Àìsáyà 3:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àwọn ọmọdékùnrin ni màá fi ṣe olórí wọn,
Àwọn aláìnípinnu* ló sì máa ṣàkóso wọn.
-