-
Jẹ́nẹ́sísì 16:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí náà, Sáráì sọ fún Ábúrámù pé: “Ìwọ lo fa ìyà tó ń jẹ mí. Èmi ni mo fa ìránṣẹ́ mi lé ọ lọ́wọ́,* àmọ́ nígbà tó rí i pé òun ti lóyún, ó wá ń fojú àbùkù wò mí. Kí Jèhófà ṣèdájọ́ èmi àti ìwọ.”
-