Ẹ́kísódù 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn eéṣú náà kún gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, wọ́n sì bo gbogbo agbègbè Íjíbítì.+ Wọ́n ṣọṣẹ́ gan-an;+ eéṣú ò tíì pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ rí, wọn ò sì ní pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ mọ́ láé. Jóẹ́lì 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ohun tí eéṣú tó ń jẹ nǹkan run jẹ kù, ni ọ̀wọ́ eéṣú jẹ;+Ohun tí ọ̀wọ́ eéṣú jẹ kù, ni eéṣú tí kò níyẹ̀ẹ́ jẹ;Ohun tí eéṣú tí kò níyẹ̀ẹ́ jẹ kù, ni ọ̀yánnú eéṣú jẹ.+
14 Àwọn eéṣú náà kún gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, wọ́n sì bo gbogbo agbègbè Íjíbítì.+ Wọ́n ṣọṣẹ́ gan-an;+ eéṣú ò tíì pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ rí, wọn ò sì ní pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ mọ́ láé.
4 Ohun tí eéṣú tó ń jẹ nǹkan run jẹ kù, ni ọ̀wọ́ eéṣú jẹ;+Ohun tí ọ̀wọ́ eéṣú jẹ kù, ni eéṣú tí kò níyẹ̀ẹ́ jẹ;Ohun tí eéṣú tí kò níyẹ̀ẹ́ jẹ kù, ni ọ̀yánnú eéṣú jẹ.+