-
Léfítíkù 11:29, 30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 “‘Àwọn ẹ̀dá tó ń rákò lórí ilẹ̀, tó jẹ́ aláìmọ́ fún yín nìyí: ẹ̀lírí, eku,+ gbogbo onírúurú aláǹgbá, 30 ọmọńlé, awọ́nríwọ́n, aláàmù, ọlọ́yọ̀ọ́ǹbẹ́rẹ́ àti ọ̀gà.
-