-
Jeremáyà 16:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹnì kankan ò ní fún àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ lóúnjẹ,
Láti tù wọ́n nínú nítorí èèyàn wọn tó kú;
Bẹ́ẹ̀ ni ẹnì kankan ò ní fún wọn ní ife wáìnì mu láti tù wọ́n nínú
Nítorí bàbá àti ìyá wọn tó ṣaláìsí.
-