ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Sámúẹ́lì sì ń ṣe ìránṣẹ́+ níwájú Jèhófà, ó wọ* éfódì tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọdékùnrin ni. 19 Bákan náà, ìyá rẹ̀ máa ń dá aṣọ àwọ̀lékè kékeré tí kò lápá fún un, a sì mú un wá fún un lọ́dọọdún nígbà tí òun àti ọkọ rẹ̀ bá wá láti rú ẹbọ ọdọọdún.+

  • Títù 2:3-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Bákan náà, kí àwọn àgbà obìnrin jẹ́ ẹni tó ń bọ̀wọ̀ fúnni, kí wọ́n má ṣe jẹ́ abanijẹ́, kí wọ́n má ṣe jẹ́ ọ̀mùtí, kí wọ́n máa kọ́ni ní ohun rere, 4 kí wọ́n lè máa gba àwọn ọ̀dọ́bìnrin níyànjú* láti nífẹ̀ẹ́ ọkọ wọn, láti nífẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ wọn, 5 láti jẹ́ aláròjinlẹ̀, oníwà mímọ́, ẹni tó ń ṣiṣẹ́ ilé,* ẹni rere, tó ń tẹrí ba fún ọkọ,+ kí àwọn èèyàn má bàa sọ̀rọ̀ àbùkù sí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́