Jóòbù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 ó wá sọ pé: “Ìhòòhò ni mo jáde látinú ikùn ìyá mi,Ìhòòhò ni màá sì pa dà.+ Jèhófà ti fúnni,+ Jèhófà sì ti gbà á. Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí lọ.”
21 ó wá sọ pé: “Ìhòòhò ni mo jáde látinú ikùn ìyá mi,Ìhòòhò ni màá sì pa dà.+ Jèhófà ti fúnni,+ Jèhófà sì ti gbà á. Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí lọ.”