Mátíù 16:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lóòótọ́, àǹfààní wo ni èèyàn máa rí tó bá jèrè gbogbo ayé àmọ́ tó pàdánù ẹ̀mí* rẹ̀?+ Àbí kí ni èèyàn máa fi dípò ẹ̀mí* rẹ̀?+ Jòhánù 6:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ẹ má ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tó ń ṣègbé, àmọ́ ẹ ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tó wà fún ìyè àìnípẹ̀kun,+ èyí tí Ọmọ èèyàn máa fún yín; torí pé Baba, ìyẹn Ọlọ́run fúnra rẹ̀, ti gbé èdìdì ìtẹ́wọ́gbà rẹ̀ lé ẹni yìí.”+
26 Lóòótọ́, àǹfààní wo ni èèyàn máa rí tó bá jèrè gbogbo ayé àmọ́ tó pàdánù ẹ̀mí* rẹ̀?+ Àbí kí ni èèyàn máa fi dípò ẹ̀mí* rẹ̀?+
27 Ẹ má ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tó ń ṣègbé, àmọ́ ẹ ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tó wà fún ìyè àìnípẹ̀kun,+ èyí tí Ọmọ èèyàn máa fún yín; torí pé Baba, ìyẹn Ọlọ́run fúnra rẹ̀, ti gbé èdìdì ìtẹ́wọ́gbà rẹ̀ lé ẹni yìí.”+