Oníwàásù 4:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo bá àwọn tó ti kú yọ̀ dípò àwọn tó ṣì wà láàyè.+ 3 Ẹni tó sàn ju àwọn méjèèjì lọ ni ẹni tí wọn ò tíì bí,+ tí kò tíì rí ohun tó ń kó ìdààmú báni tí à ń ṣe lábẹ́ ọ̀run.*+
2 Mo bá àwọn tó ti kú yọ̀ dípò àwọn tó ṣì wà láàyè.+ 3 Ẹni tó sàn ju àwọn méjèèjì lọ ni ẹni tí wọn ò tíì bí,+ tí kò tíì rí ohun tó ń kó ìdààmú báni tí à ń ṣe lábẹ́ ọ̀run.*+