Sáàmù 119:71 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 71 Ó dára bí a ṣe fìyà jẹ mí,+Kí n lè kọ́ àwọn ìlànà rẹ. Lúùkù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Aláyọ̀ ni ẹ̀yin tí ebi ń pa báyìí, torí pé ẹ máa yó.+ “Aláyọ̀ ni ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sunkún báyìí, torí pé ẹ máa rẹ́rìn-ín.+
21 “Aláyọ̀ ni ẹ̀yin tí ebi ń pa báyìí, torí pé ẹ máa yó.+ “Aláyọ̀ ni ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sunkún báyìí, torí pé ẹ máa rẹ́rìn-ín.+