1 Sámúẹ́lì 25:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Lẹ́yìn náà, Ábígẹ́lì pa dà sọ́dọ̀ Nábálì, ó ń jẹ àsè lọ́wọ́ nínú ilé rẹ̀ bí ọba, inú Nábálì* ń dùn, ó sì ti mutí yó bìnàkò. Àmọ́ obìnrin náà kò sọ nǹkan kan fún un títí ilẹ̀ fi mọ́. Òwe 21:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ fàájì* yóò di aláìní;+Ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ wáìnì àti òróró kò ní lówó lọ́wọ́.
36 Lẹ́yìn náà, Ábígẹ́lì pa dà sọ́dọ̀ Nábálì, ó ń jẹ àsè lọ́wọ́ nínú ilé rẹ̀ bí ọba, inú Nábálì* ń dùn, ó sì ti mutí yó bìnàkò. Àmọ́ obìnrin náà kò sọ nǹkan kan fún un títí ilẹ̀ fi mọ́.