Òwe 4:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní ọgbọ́n, ní òye.+ Má gbàgbé, má sì kúrò nínú ohun tí mo sọ. 6 Má pa á tì, yóò dáàbò bò ọ́. Nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, yóò sì pa ọ́ mọ́.
5 Ní ọgbọ́n, ní òye.+ Má gbàgbé, má sì kúrò nínú ohun tí mo sọ. 6 Má pa á tì, yóò dáàbò bò ọ́. Nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, yóò sì pa ọ́ mọ́.