Jémíìsì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣé ẹnikẹ́ni wà láàárín yín tí nǹkan nira fún? Kó má ṣe dákẹ́ àdúrà.+ Ṣé ẹnikẹ́ni wà láàárín yín tí inú rẹ̀ ń dùn? Kó máa kọ sáàmù.+
13 Ṣé ẹnikẹ́ni wà láàárín yín tí nǹkan nira fún? Kó má ṣe dákẹ́ àdúrà.+ Ṣé ẹnikẹ́ni wà láàárín yín tí inú rẹ̀ ń dùn? Kó máa kọ sáàmù.+