ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 65:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Wọ́n sọ pé, ‘Dúró sí àyè rẹ; má ṣe sún mọ́ mi,

      Torí mo mọ́ jù ọ́ lọ.’*

      Èéfín ni àwọn yìí nínú ihò imú mi, iná tó ń jó láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.

  • Mátíù 6:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Kí ẹ rí i pé ẹ ò ṣe òdodo yín níwájú àwọn èèyàn, torí kí wọ́n lè rí yín;+ àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ẹ ò ní rí èrè kankan lọ́dọ̀ Baba yín tó wà ní ọ̀run.

  • Róòmù 10:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Bí wọn ò ṣe mọ òdodo Ọlọ́run,+ àmọ́ tó jẹ́ pé bí wọ́n á ṣe gbé tiwọn kalẹ̀ ni wọ́n ń wá,+ wọn ò fi ara wọn sábẹ́ òdodo Ọlọ́run.+

  • Róòmù 14:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ kí ló dé tí o fi ń dá arákùnrin rẹ lẹ́jọ́?+ Tàbí kí ló dé tí ò ń fojú àbùkù wo arákùnrin rẹ? Nítorí gbogbo wa la máa dúró níwájú ìjókòó ìdájọ́ Ọlọ́run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́