Òwe 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara rẹ.+ Bẹ̀rù Jèhófà kí o sì yẹra fún ibi. Róòmù 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi, mo sọ fún gbogbo ẹni tó wà láàárín yín níbẹ̀ pé kó má ro ara rẹ̀ ju bó ṣe yẹ lọ,+ àmọ́ kó máa ronú lọ́nà tó fi hàn pé ó láròjinlẹ̀, bí Ọlọ́run ṣe fún kálukú ní ìwọ̀n ìgbàgbọ́.*+
3 Torí nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi, mo sọ fún gbogbo ẹni tó wà láàárín yín níbẹ̀ pé kó má ro ara rẹ̀ ju bó ṣe yẹ lọ,+ àmọ́ kó máa ronú lọ́nà tó fi hàn pé ó láròjinlẹ̀, bí Ọlọ́run ṣe fún kálukú ní ìwọ̀n ìgbàgbọ́.*+