- 
	                        
            
            Oníwàásù 2:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 Mo wá fiyè sí ọgbọ́n àti ìwà wèrè àti ìwà ẹ̀gọ̀.+ (Kí ni ẹni tó máa wá lẹ́yìn ọba lè ṣe? Ohun tí àwọn èèyàn ti ṣe tẹ́lẹ̀ ni.) 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Oníwàásù 7:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        25 Mo darí ọkàn mi kí n lè mọ̀, kí n lè wádìí, kí n sì lè wá ọgbọ́n àti ohun tó ń fa àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀, mo sì darí rẹ̀ kí n lè lóye aburú tó wà nínú ìwà ẹ̀gọ̀ àti àìlọ́gbọ́n tó wà nínú ìwà wèrè.+ 
 
-