Róòmù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, ìdí pàtàkì wà tó fi yẹ kí ẹ máa tẹrí ba, kì í ṣe nítorí ìrunú yẹn nìkan, àmọ́ ó jẹ́ nítorí ẹ̀rí ọkàn+ yín pẹ̀lú. 1 Pétérù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Lóòótọ́, ta ló máa ṣe yín léṣe tí ẹ bá ń fi ìtara ṣe ohun rere?+
5 Torí náà, ìdí pàtàkì wà tó fi yẹ kí ẹ máa tẹrí ba, kì í ṣe nítorí ìrunú yẹn nìkan, àmọ́ ó jẹ́ nítorí ẹ̀rí ọkàn+ yín pẹ̀lú.