Jóòbù 7:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Bí ìkùukùu tó ń pa rẹ́ lọ, tó sì wá pòórá,Ẹni tó lọ sí Isà Òkú* kì í pa dà wá.+ 10 Kò ní pa dà sí ilé rẹ̀ mọ́,Ibùgbé rẹ̀ kò sì ní mọ̀ ọ́n mọ́.+ Oníwàásù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí a kì í rántí ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀ títí lọ.+ Bó pẹ́ bó yá, a ò ní rántí ẹnikẹ́ni mọ́. Báwo sì ni ọlọ́gbọ́n ṣe máa kú? Á kú pẹ̀lú àwọn òmùgọ̀.+
9 Bí ìkùukùu tó ń pa rẹ́ lọ, tó sì wá pòórá,Ẹni tó lọ sí Isà Òkú* kì í pa dà wá.+ 10 Kò ní pa dà sí ilé rẹ̀ mọ́,Ibùgbé rẹ̀ kò sì ní mọ̀ ọ́n mọ́.+
16 Nítorí a kì í rántí ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀ títí lọ.+ Bó pẹ́ bó yá, a ò ní rántí ẹnikẹ́ni mọ́. Báwo sì ni ọlọ́gbọ́n ṣe máa kú? Á kú pẹ̀lú àwọn òmùgọ̀.+