- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 4:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        25 Júdà àti Ísírẹ́lì ń gbé lábẹ́ ààbò ní gbogbo ọjọ́ ayé Sólómọ́nì, kálukú lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀, láti Dánì títí dé Bíá-ṣébà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Orin Sólómọ́nì 8:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Sólómọ́nì ní ọgbà àjàrà+ kan ní Baali-hámọ́nì. Ó gbé ọgbà àjàrà náà fún àwọn tí á máa tọ́jú rẹ̀. Kálukú wọn á máa mú ẹgbẹ̀rún (1,000) ẹyọ fàdákà wá fún èso rẹ̀. 
 
-