Òwe 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Aláròjinlẹ̀ máa ń fi ìmọ̀ hùwà,+Àmọ́ òmùgọ̀ máa ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.+ Òwe 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹnu òmùgọ̀ ni ìparun rẹ̀,+Ètè rẹ̀ sì jẹ́ ìdẹkùn fún ẹ̀mí* rẹ̀.