Oníwàásù 8:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo ní: “Pa àṣẹ ọba mọ́+ nítorí o ti búra níwájú Ọlọ́run.+ 3 Má ṣe yára kúrò níwájú rẹ̀.+ Má ṣe lọ́wọ́ sí ohunkóhun tó burú;+ torí ohun tó bá wù ú ló lè ṣe,
2 Mo ní: “Pa àṣẹ ọba mọ́+ nítorí o ti búra níwájú Ọlọ́run.+ 3 Má ṣe yára kúrò níwájú rẹ̀.+ Má ṣe lọ́wọ́ sí ohunkóhun tó burú;+ torí ohun tó bá wù ú ló lè ṣe,