-
1 Àwọn Ọba 12:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àmọ́, ńṣe ni ọba jágbe mọ́ àwọn èèyàn náà, kò gba ìmọ̀ràn tí àwọn àgbà ọkùnrin* fún un. 14 Ìmọ̀ràn tí àwọn ọ̀dọ́kùnrin fún un ló tẹ̀ lé, ó sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Bàbá mi mú kí àjàgà yín wúwo, ṣùgbọ́n ṣe ni màá fi kún àjàgà yín. Pàṣán ni bàbá mi fi nà yín, ṣùgbọ́n kòbókò oníkókó ni màá fi nà yín.”
-