-
2 Kíróníkà 13:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn ọkùnrin aláìríkan-ṣèkan àti aláìníláárí ń kóra wọn jọ sọ́dọ̀ rẹ̀. Wọ́n borí Rèhóbóámù ọmọ Sólómọ́nì nígbà tí Rèhóbóámù ṣì jẹ́ ọ̀dọ́, tó sì ya ojo, kò sì lè dojú kọ wọ́n.
-