Òwe 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọ̀lẹ kì í túlẹ̀ nígbà òtútù,Tó bá dìgbà ìkórè, á máa tọrọ torí pé kò ní nǹkan kan.*+