Oníwàásù 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí náà, rántí Ẹlẹ́dàá rẹ Atóbilọ́lá nígbà ọ̀dọ́ rẹ,+ kí àwọn ọjọ́ wàhálà* tó dé,+ kí àwọn ọdún náà tó dé nígbà tí wàá sọ pé: “Wọn ò mú inú mi dùn”;
12 Nítorí náà, rántí Ẹlẹ́dàá rẹ Atóbilọ́lá nígbà ọ̀dọ́ rẹ,+ kí àwọn ọjọ́ wàhálà* tó dé,+ kí àwọn ọdún náà tó dé nígbà tí wàá sọ pé: “Wọn ò mú inú mi dùn”;