-
Sáàmù 25:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Má ṣe rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ìgbà èwe mi àti àwọn àṣìṣe mi.
-
-
2 Tímótì 2:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Torí náà, sá fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ìgbà ọ̀dọ́, àmọ́ máa wá òdodo, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, àlàáfíà, pẹ̀lú àwọn tó ń fi ọkàn tó mọ́ ké pe Olúwa.
-