-
Ìṣe 2:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ó gún wọn dé ọkàn, wọ́n sì sọ fún Pétérù àti àwọn àpọ́sítélì yòókù pé: “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará, kí ni ká ṣe?”
-